1. Iwáró: Two people that escort a new wife to her husband's house
2. Alágbe: A person who sings and dances for money
3. Onísòwò: Someone that is into buying and selling
4. Àgbẹ̀: A farmer
5. Agbẹjọ́rò: A lawyer
6. Alágbẹ̀dẹ: A smith
7. Babaláwo: An ifa priest
8. Ọ̀tá: An enemy
9. Alápatà: A butcher
10. Pẹjapẹja: A fisher
11. Àyò: A favorite
12. Òbùrẹwà: An ugly person
13. Aláròká: A rumour monger or talebearer
14. Onírìkísí or Ọlọ̀tẹ̀: A dilly dally person or someone that plots conspiracy or a betrayal
15. Wọ̀bìà or Alájẹjù: A glutton
16. Alámupara: A drunkard
17. Arúfin: A defaulter
18. Ẹlẹ́wọ̀n: A prisoner
19. Alágbàtọ́: A carer or nanny
20. Alákọ́bẹ̀rẹ̀: A beginner
21. Ọlọ́pàá: Police
22. Rélùwéé: Railway
23. Mọlémọlé: A builder or bricklayer
24. Gbẹ́nàgbẹ́nà: A carpenter
25. Olùgbìfọ̀: A translator
26. Alágbàfọ̀: A laundry man
27. Onígbàjamọ̀: A barber
28. Jagunjagun: A warrior
29. Oníwòsìwósì: A petty trader
30. Elébìrà: A worker or labourer
31. Alárinà: A match maker or an intermediary
32. Arẹwà: A beautiful person
33. Akọ̀wé: An educated person
34. Adájọ́: A judge
35. Ẹrú: A slave
36. Òkóbó Akúra: An impotent man
37. Orò: A masqurade festival that a woman must not see.
Saturday, July 7, 2018
Yoruba Proverbs and Their Meaning
1. Ẹnu ò mẹnu, ètè ò métè ní kó ọ̀ràn bá ẹ̀rẹ̀kẹ́
Meaning: Excessive talk brings insult.
2. Ẹni t'ó yá ẹgbẹ̀fà tí kò san, o bẹ́gi dínà ẹgbàá
Meaning: A person who has defaulted on repaying 1,200 disqualifies himself or herself from a credit of 2,000 from the same source.
3. Ẹni tó sọ pé kárá ilé òun má là, ará òde ní yóò yaa lọ́fà
Meaning: He who wishes poverty for his or her relations will end up as a bond-man in the hands of strangers
4. Ẹni tó lẹlẹ́dẹ̀ ló lẹ̀ẹ̀dẹ̀
Meaning: The owner of the pigs owns or dominates the compound.
5. Ẹni tó jogún kógún, ìtàn kítàn ni yóò máa pa
Meaning: He or she who illicitly inherits will live to tell fictitious stories to back up his or her illegal act.